Adura By Babatunmise (Lyrics) | @iambabatunmise - Pricherman116.com | Nigerian / Foreign Gospel Songs | Christian Hip Hop | News | Interviews | Events

Search For Gospel Music | Lyrics | Events | News...

HOT POSTS

Post Top Ad


June 26, 2017

Adura By Babatunmise (Lyrics) | @iambabatunmise


Chorus

Jiji mo ji l'owuro
Orin ope mo mu wa
Mo w'ole
N'iwaju re
Baba gb'ope mi
Lilo bibo mi baba
Mo fi le O l'owo o
Ma je n rin l'ojo t'ebi n pa'no
Angeli mi, maa so mi lo ooo
Je ki n pade alaanu mi
Je k'idunu ma gbe'nu mi
Orin ope l'enu mi

Chorus:

Adura ni mo gba
T'ogun aye fi wo
Adura ni mo gba
T'ona mi fi la o
Adura ni mo gba o
T'aye mi fi dara
Ohun owo o le se
Adura lo ma se


Watch BBT's ministration at MASS 4.0 (Akure);


Verse 2:

Emi o gb'oju mi
Sori oke wonni
Nibi t'iranwo mi yo ha ti wa
Agbara ko, eniyan ko
Oba mi orun lo semilore
Adura ti mo gba lojosi i
S'ohun l'Oluwa fi da mi si i
Orun ti gbo, ase ti gun
Igbagbo mi s'omi d'otun
Igbagbo mi s'omi d'otun
Adura l'opa Kristiani
Adura l'agbara ti mo gb'oju le...

(Modulate)

Chorus:

Adura ni mo gba
T'ogun aye fi wo
Adura ni mo gba
T'ona mi fi la o
Adura ni mo gba o
T'aye mi fi dara
Ohun owo o le se
Adura lo le se

Bridge:

B'iberu ba mu onigbagbo f'oya
Adura lo le se
Bi ogun Pharaoh ba b'ija l'eni
Adura lo le se
Bi araye bere p'Olorun mi da
Adura lo le se
Nigba riri je, nigba airi je
Adura lo le se

Chorus:

Adura ni mo gba
T'ogun aye fi wo
Adura ni mo gba
T'ona mi fi la o
Adura ni mo gba o
T'aye mi fi dara
Ohun owo o le se
Adura lo ma se

Aadura lo ma se....


Adura was produced by Tyanx

No comments:

Post a Comment

Post Bottom Ad